Ìwé agbedegbẹyọ fun awọn hadiisi Anọbi ti a tu si èdè mìíràn

Iṣẹ́ àkànṣe ti o n rí si pípèsè àwọn àlàyé ti o rọrùn ati awọn ìtumọ̀ ti o hàn fún àwọn hadiisi Anọbi ti o ni àlàáfíà

API +400 Million API Calls

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn hadiisi

Àlékún
Àwọn iṣẹ pẹ̀lú àwọn àníyàn ni, o maa jẹ ti ọmọniyan kọ̀ọ̀kan ohun ti o ba gba lero
Ẹni ti o ba da adadaalẹ kalẹ sinu alamọri wa yii ninu nnkan ti ko si nibẹ, wọn maa da a pada ni
Isilaamu ni ki o jẹ́rìí pe ko si ẹni tí ìjọsìn tọ si lododo ayafi Ọlọhun, ati pe Muhammad ni ojiṣẹ Rẹ, ki o maa gbe ìrun dúró, ki o maa yọ sàká, ki o maa gba aawẹ Ramadan, ki o maa ṣe hajj ti o ba ni ikapa ọ̀nà lọ si ibẹ
Wọn mọ Isilaamu pa lori nkan márùn-ún
Dajudaju iwọ Ọlọhun lori awọn ẹrusin ni ki wọn maa jọsin fun Un ki wọn si ma da nnkan
Ko si ẹni kankan ti o n jẹrii pe ko si ẹni ti ijọsin tọ si lododo afi Allahu, ati pe Muhammad ojiṣẹ Ọlọhun ni lododo lati inu ọkan rẹ, afi ki Ọlọhun ṣe ina leewọ fun un
“Ẹni ti o ba sọ pe: LAA ILAAHA ILLALLOHU, ti o wa ṣe aigbagbọ pẹlu nnkan ti wọn n jọsin fun yatọ si Ọlọhun, dukia rẹ ati ẹjẹ rẹ ti jẹ eewọ, ati pe ìṣirò rẹ wa lọ́wọ́ Ọlọhun”
Ẹni ti o ba ku ti ko da ẹbọ kankan pọ mọ Ọlọhun yoo wọ alujanna, ẹni ti o ba si ku ti o da ẹbọ pọ mọ Ọlọhun yoo wọ ina
Ẹni ti o ba ku ti o si n pe akẹgbẹ kan ti o yàtọ̀ si Ọlọhun, o maa wọ ina
Iwọ yoo lọ sí ọdọ awọn eniyan kan ti wọ́n jẹ́ oni-tira sánmọ̀, tí o bá dé ọdọ wọn, pẹ̀ wọn kí o sọ fún wọn pé kí wọ́n jẹrii pé dajudaju ko si ọlọhun miran ayafi Ọlọhun Allah, ati pé dajudaju Anabi Muhammad Ojiṣẹ Ọlọhun ní n ṣe
Àwọn àfojúsùn

Iṣẹ́ àkànṣe ìwé gbédègbẹ́yọ̀ àwọn Hadiisi Anọbi àti ìtumọ̀ wọn sí èdè mìíràn

Iṣẹ́ àkànṣe kan ti o pé lati sẹsa awọn ọrọ Anabi ti wọn paara ninu àkóónú Isilaamu ati ṣiṣe àlàyé rẹ pẹlu àwòrán tí o ye yekeyeke ti o si pe, lẹyin naa títú u ni ọ̀nà ti o dára gan-an ni ìbámu sí àwọn ìlànà tí o ṣe deede sí awọn èdè tí wọ́n bóde mu, ati jijẹ kí ó wà ní àrọ́wọ́tó ni ọfẹ pẹlu gbogbo ọ̀nàkọnà ti o bá wà ní ìkáwọ́.

Iṣe-awari itọkasi agbaye ti o jẹ ọfẹ ti o ṣe e gbẹkẹle ti o ti gberu fún àwọn ìtumọ Hadiisi Anọbi sí èdè mìíràn:

Pipese mẹ́mórì ti kọnputa fún titumọ awọn hadiisi si èdè mìíràn, sí arọwọto àwọn olutumọ ni igbati wọn ba n ṣe ìtumọ̀ si èdè mìíràn.

Mímú àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn dé ọ̀dọ̀ àwọn tí a fẹ́ ki o de ọdọ wọn pẹ̀lú gbogbo ọ̀nà ti o bá rọrùn

Download the encyclopedia content

Download the Prophetic Hadith Encyclopedia content for free, in the language and format you need.

Downloading files indicates acceptance of the Terms and Policies
AR العربية Arabic Excel CSV SQLite
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì Excel CSV SQLite
FR Français Èdè Faransé Excel CSV SQLite
ES Español Èdè Sípéènì Excel CSV SQLite
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà Excel CSV SQLite
BN বাংলা Èdè Bangali Excel CSV SQLite
UR اردو Èdè Urdu Excel CSV SQLite
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur Excel CSV SQLite
HA Hausa Èdè Hausa Excel CSV SQLite
KU Kurdî Ti Kurdish Excel CSV SQLite
TL Tagalog Èdè Tagalog Excel CSV SQLite
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese Excel CSV SQLite
FA فارسی Èdè Páṣíà Excel CSV SQLite
ZH 中文 Èdè Ṣáínà Excel CSV SQLite
HI हिन्दी Èdè India Excel CSV SQLite
SI සිංහල Èdè Sinhala Excel CSV SQLite
BS Bosanski Èdè Bosnia Excel CSV SQLite
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà Excel CSV SQLite
TR Türkçe Èdè Tọ́kì Excel CSV SQLite
PT Português Ti Pọtuga Excel CSV SQLite
ML മലയാളം Malayalam Excel CSV SQLite
TE తెలుగు Èdè Telgu Excel CSV SQLite
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili Excel CSV SQLite
TA தமிழ் Tamil Excel CSV SQLite
MY မြန်မာ Burmese Excel CSV SQLite
TH ไทย Thai Excel CSV SQLite
JA 日本語 Ará Japan Excel CSV SQLite
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz Excel CSV SQLite
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal Excel CSV SQLite
DE Deutsch Ede Jamani Excel CSV SQLite
PS پښتو Pashto Excel CSV SQLite
AS অসমীয়া Assamese Excel CSV SQLite
SQ Shqip Ede Alibania Excel CSV SQLite
SV Svenska Titi Sweden Excel CSV SQLite
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic Excel CSV SQLite
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch Excel CSV SQLite
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat Excel CSV SQLite
YO Yorùbá Èdè Yorùbá Excel CSV SQLite
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania Excel CSV SQLite
PRS دری Ti èdè Dari Excel CSV SQLite
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia Excel CSV SQLite
SO Soomaali Ti èdè Somalia Excel CSV SQLite
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan Excel CSV SQLite
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda Excel CSV SQLite
RO Română Ti èdè ìlú Romania Excel CSV SQLite
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary Excel CSV SQLite
CS Čeština Ti èdè Czech Excel CSV SQLite
MOS Moore الموري Excel CSV SQLite
MG Malagasy Ti ede Madagascar Excel CSV SQLite
FF Fulfulde Ti èdè Fulani Excel CSV SQLite
IT Italiano Ti ede ilu Italy Excel CSV SQLite
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo Excel CSV SQLite
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada Excel CSV SQLite
WO Wolof الولوف Excel CSV SQLite
BG Български البلغارية Excel CSV SQLite
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan Excel CSV SQLite
EL Ελληνικά اليونانية Excel CSV SQLite
AK Akan الأكانية Excel CSV SQLite
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan Excel CSV SQLite
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine Excel CSV SQLite
KA ქართული الجورجية Excel CSV SQLite
LN Lingala اللينجالا Excel CSV SQLite
MK Македонски المقدونية Excel CSV SQLite
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية Excel CSV SQLite
BM Bambara البامبارية Excel CSV SQLite
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية Excel CSV SQLite
MR मराठी الماراثية Excel CSV SQLite
DA Dansk الدنماركية Excel CSV SQLite
RN Kirundi الكيروندي Excel CSV SQLite
YAO Yao الياو Excel CSV SQLite
KMR Kurmancî الكرمنجية Excel CSV SQLite
MS Bahasa Melayu الملايو Excel CSV SQLite

Our Key Statistics

Explore the latest figures that reflect our reach and engagement with our content. The impact of knowledge and inspiration is visible in our numbers.

More statistics
50+ Languages Supported by the encyclopedia
15+ Million Visits annually
5+ Million API calls monthly
40+ Thousand Translated Hadiths