1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Itan ìgbésí ayé

Hadiisi Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ

عَنْ عَائِشَةَ أُمِّ المُؤْمِنين رَضِيَ اللَّهُ عَنْهَا، قَالَتْ:
مَا رَأَيْتُ النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ مُسْتَجْمِعًا قَطُّ ضَاحِكًا، حَتَّى أَرَى مِنْهُ لَهَوَاتِهِ، إِنَّمَا كَانَ يَتَبَسَّمُ.

Lati ọdọ iya awọn olugbagbọ ododo, A'isha ki Ọlọhun bawa yọnu sì i, o sọ bayi pe:
Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ.

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 6092

Àlàyé

Ki Ọlọhun bá wa yọnu si A'isha, Oun ló fún wa niro pe Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - Kii mọn fi gbogbo ara rẹrin ti a fi waa rí belubelu rẹ, (belubelu ni ẹran ti o so mọ oke ọ̀nà ọ̀fun) ṣugbọn Anọbi aa maa rẹrin musẹ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Òjíṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - itumusẹ ni ẹrin rẹ nigbati o bá yọnu tabi ti nkankan ba wun un.
  2. Alufa Ọmọ Hajar so fún wa pé : mi o ri ko fi gbogbo ara rẹ rin , ni a bala erin , ti yóò fi gbogbo enu ati ara rerin .
  3. Ọpọlọpọ ẹrin, ati igbe ohun soke lati rẹ́rìn keekee kò sí ninu iroyin awọn ẹni rere.
  4. Ọpọlọpọ ẹrin aa máa gba ọwọ àti ìbẹ̀rù kuro lara eniyan laarin awọn ọmọ ìyá rẹ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

50 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية