1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi “Ayé ìgbádùn ni, eyi ti o loore ju ninu ìgbádùn ayé ni obìnrin rere”

عن عبد الله بن عمرو رضي الله عنهما أن رسول الله صلى الله عليه وسلم قال:
«الدُّنْيَا مَتَاعٌ، وَخَيْرُ مَتَاعِ الدُّنْيَا الْمَرْأَةُ الصَّالِحَةُ».

Láti ọ̀dọ̀ Abdullah ọmọ Amr- ki Ọlọhun yọnu si àwọn mejeeji- pe ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé:
“Ayé ìgbádùn ni, eyi ti o loore ju ninu ìgbádùn ayé ni obìnrin rere”

O ni alaafia Muslim gba a wa Sọhiihu ti Muslim - 1467

Àlàyé

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé ayé pẹ̀lú nǹkan ti n bẹ ninu ẹ jẹ nǹkan ti eeyan maa n gbádùn fun ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn naa ni o maa kúrò, ati pe ìgbádùn rẹ ti o ni ọlá jù ni obìnrin rere, eyi ti o ṣe pe ti o ba wo o yoo dun un ninu, ti o ba pa a láṣẹ yoo tẹle e, ti ko ba si ni tòsí o maa ṣọ́ ọ ninu ẹ̀mí ara rẹ ati dúkìá rẹ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ìní ẹtọ ìgbádùn àwọn nǹkan ti o dáa ni ayé, eyi ti Ọlọhun ṣe ni ẹtọ fun awọn ẹru Rẹ láìsí ìná-àpà tabi ìgbéraga.
  2. Ṣiṣenilojukokoro lori yíyan ìyàwó rere; tori pe iranlọwọ ni in fun ọkọ lati tẹle àṣẹ Olúwa rẹ.
  3. Eyi ti o loore julọ ninu ìgbádùn ayé ni eyi ti o ba wa fun itẹle àṣẹ Ọlọhun, tabi ti o ṣe iranlọwọ lati tẹle àṣẹ Ọlọhun.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

64 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
JA 日本語 Ará Japan
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
SO Soomaali Ti èdè Somalia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
FF Fulfulde Ti èdè Fulani
IT Italiano Ti ede ilu Italy
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
BG Български البلغارية
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
BM Bambara البامبارية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
YAO Yao الياو
KMR Kurmancî الكرمنجية