1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi Mo bi Aishah leere, mo sọ pé: kini nkan akọkọ ti Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba) ma nṣe ti o ba wọlé rẹ? Aishah daun pe: yoo kọkọ rin pako

عَنِ شُرَيْحٍ بنِ هانِئٍ قَالَ:
سَأَلْتُ عَائِشَةَ، قُلْتُ: بِأَيِّ شَيْءٍ كَانَ يَبْدَأُ النَّبِيُّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ إِذَا دَخَلَ بَيْتَهُ؟ قَالَتْ: بِالسِّوَاكِ.

Lati ọdọ shureih ọmọ Haani'i o sọ pé:
Mo bi Aishah leere, mo sọ pé: kini nkan akọkọ ti Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba) ma nṣe ti o ba wọlé rẹ? Aishah daun pe: yoo kọkọ rin pako.

O ni alaafia Muslim gba a wa Sọhiihu ti Muslim - 253

Àlàyé

O tiwa ninu imọna Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati Ọla Rẹ máa ba a) pé kí o kọkọ rin pako ti o ba wọlé rẹ ni eyi keyi asiko ni oru tabi ọsan.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ṣíṣe rinrun pako ni ilana ẹṣin ni gbogbo awọn asiko lapapọ, sise bẹ wa di nkan ti a kanpa mọ: ni awọn asiko ti asofin fẹ kí a run Pako, ninu awọn asiko naa ni: igbati a ba wọlé, nigbati a ba fẹ kirun, nigbati a ba fẹ se aluwala, ati nigbati a ba ji, ati nigbati oorun ẹnu ba yi padà.
  2. Ise alaye ìfẹ awọn ti wọn tẹle awọn saabé sí bibeerè nípa isesí Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba) ati ilana rẹ, ki wọn lè máa kọse rẹ.
  3. Gbígba ìmọ lati ọdọ awan ti wan ni ati lọdọ ẹni tí o mọ nipa rẹ julọ, nipa ibere ti wan bi Aisha ki Ọlọhun yonu si ni pá isesi Anọbi ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bá nigbati o bá wọlé.
  4. Dídá ibase pọ Annabi ki ikẹ Ọlọhun ati ola rẹ máa bá pẹlu awọn ara ilé rẹ, nipa pẹ a máà fò enu rẹ mọ ni o ba to wole.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

50 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية