1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jade lati ọwọ ahun ni”

عَنِ ابْنِ عُمَرَ رضي الله عنهما:
عَنِ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ أَنَّهُ نَهَى عَنِ النَّذْرِ، وَقَالَ: «إِنَّهُ لَا يَأْتِي بِخَيْرٍ، وَإِنَّمَا يُسْتَخْرَجُ بِهِ مِنَ الْبَخِيلِ».

Lati ọdọ ọmọ Umar ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji:
Lati ọdọ Anabi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a- dajudaju o kọ kuro nibi ẹjẹ jijẹ, o wa sọ pe: “Dajudaju ẹjẹ jijẹ o ki n mu oore wa, bi ko ṣe pe wọn maa n fi gba nnkan jade lati ọwọ ahun ni”.

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Muslim - 1639

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- kọ kuro nibi ileri, oun ni ki eniyan ṣe nnkan kan ni dandan fun ara rẹ ti Ọba aṣofin ko ṣe ni dandan fun un, o sọ pe: Nitori pe ileri ko ti nnkan ṣíwájú ko si lọ ọ lara, bi ko ṣe pe wọn maa n mu u jade lati ọdọ ahun ti ko ki n ṣe nnkan kan afi nnkan ti o jẹ dandan le e lori, ati pe dajudaju ileri ko ki n mu nnkan kan wa ti wọn ko tii kadara rẹ fun un.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Wọn ko ṣe ileri ṣiṣe ni ofin, ṣùgbọ́n ti o ba ti ṣe ileri mimu u ṣẹ ti jẹ dandan fun un ti ko ba ti jẹ ẹ̀ṣẹ̀.
  2. Idi to fa kikọ ni (oun ni pe ko ki n wa pẹlu dáadáa); nitori pe ko ki n da nnkan kan pada ninu idajọ Ọlọhun; ki oluṣe ileri ma lọ lero pe wiwaye nnkan ti o beere fun ribẹ pẹlu okunfa ileri náà, ati pe Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- rọrọ kuro nibi iyẹn.
  3. Al-Qurtubiy sọ pe: Kikọ yii aaye rẹ ni ki o sọ ni àpẹẹrẹ pe: Ti Ọlọhun ba wo alaisan mi san saara bayii jẹ dandan le mi lori, ati pe oju pọnna kikọ ni pe nigba ti o ṣe pe ṣiṣe nnkan asunmọ ti a darukọ naa duro lori ṣiṣẹlẹ erongba ti a darukọ, o han pe aniyan asunmọ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- ko fi ẹsẹ rinlẹ fun un, fun nnkan ti o waye lati ọwọ rẹ bi ko ṣe pe o tọ oju ọna fi kan gba ikan, o si n fi I han pe ti ko ba wo alaisan rẹ san ko nii ṣe saara pẹlu nnkan ti o so o pọ mọ lori wiwo o san, eleyii si nii iṣesi ahun, nitori pe ko nii mu nnkan kan jade ninu dukia rẹ afi pẹlu ijirọ kiakia ti yoo lekun lori nnkan ti o mu jade lọpọlọpọ igba.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

55 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
SO Soomaali Ti èdè Somalia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية