1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi kò lẹtọ láti ta ẹjẹ musulumi kankan silẹ ayaafi pẹlu ọkan nínú nkan mẹta

عَنِ ابنِ مَسعُودٍ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قَالَ: قَالَ رَسُولُ اللهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ:
«لَا يَحِلُّ دَمُ امْرِئٍ مُسْلِمٍ إِلَّا بِإِحْدَى ثَلَاثٍ: الثَّيِّبُ الزَّانِي، وَالنَّفْسُ بِالنَّفْسِ، وَالتَّارِكُ لِدِينِهِ المُفَارِقُ لِلْجَمَاعَةِ».

Láti ọdọ Ibnu Mas'ud kí Ọlọhun yọnu si; o s'ọpé: Òjíṣẹ́ Ọlọhun kí ikẹ àti ọla Ọlọhun máa ba a s'ọpe:
«kò lẹtọ láti ta ẹjẹ musulumi kankan silẹ ayaafi pẹlu ọkan nínú nkan mẹta: Adelebọ tàbí Abilekọ l'óbìnrin tàbí l'ọkunrin tí o ba se zina, ati ẹmi kan tí o pa ẹmi keji lai l'ẹtọ, àti ẹni tí o fi ẹṣin ṣílẹ tí o si yapa kuro ninu awujọ (awọn musulumi)".

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Muslim - 1676

Àlàyé

Annabi -kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ o máa ba a- ṣe alaye pé eewọ ni lati ta ẹjẹ musulumi silẹ, àyàfi tí o ba ṣe ọkan nínú awọn nkan mẹta (wọnyi): Alakọkọ: ẹni tí o ba ṣe àgbèrè (zina), tí o si jasi pe o ti ṣe ìgbeyàwó l'ọna tí o lalaafia, nigbanaa o tọ kí a o sọ l'oko pa (titi ti ẹmi o fi bọ lara rẹ). Ẹlẹẹkeji: ẹnikẹni ti o ba maama pa ẹmi kan (ti a se l'eewọ lati pa) laisi ẹtọ, a o pa oun naa di pẹlu awọn majẹmu (ati ofin) ti o ro papọ mọ. Ẹlẹkẹta: ẹni tí o ba yapa kúrò láàrin awujọ awọn musulumi, bóyá nipa fífi ẹṣin Islam silẹ nipasẹ (Ridda), tabi ẹni tí o nya pá l'ọtọ lai ṣe (Ridda) nipasẹ fífi apakan (ofin Islam) silẹ, gẹgẹ bi awọn obilẹjẹ ènìyàn, àti awọn adigun jàle, ati awọn olujagun nínú àwọn Khawaarij àti awọn miran.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ṣíṣe awọn nkan mẹtẹta wọnyí l'ewọ, àti pé dájúdájú ẹnikẹni tí o ba ṣe ọkan nínú wọn yio tọsi ijiyà pipá: yálà nitori (kufuru) igbe ẹsin Islam ju silẹ, tàbí kí o jẹ fún ìbáwí (Al-Haddu); fún iran kan ninu iran eniyan meji: abilekọ tàbí adelebọ (l'ọkunrin tabi l'obirin) tí o ṣe àgbèrè (zina), ati ẹni tí o maama pa ẹmi (ti a ṣe l'ewọ lati pa).
  2. Ọranyan kí a sọ ijẹ́ ọmọluabi àti mimọ rẹ.
  3. Ọranyan bíbọwọ/iṣe apanle fún musulumi, àti pé a se ẹjẹ rẹ l'ewọ.
  4. Iṣeni ni ojúkòkòrò lórí iduró ṣinsín ninu awujọ awọn musulumi àti pe kí a má ṣe y'apa kuro ninu wọn.
  5. Dídára ìkọni lẹkọ Annabi -kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ o máa ba a- látara pé a máa mú ọrọ rẹ wa nigbami ni ọnà pínpín, nítorípé pínpín ọrọ (lẹka lẹka) a máa ṣe akopọ àti akotan ọrọ (imọ), a si maa yara láti ṣe e há sí ọpọlọ.
  6. Ọlọhun ṣe ìjẹni nìyà (ìbáwí) l'ofin; láti fi dẹkun awọn olu-dẹsẹ, àti láti fi dáàbò bo àwùjọ, bakannaa lati fi sọ (àwùjọ) nibi awọn iwa ọdaran.
  7. Ṣíṣe amulo awọn ìdájọ ìjẹni niyà (ìbáwí) wa ninu ojuṣe Olori ni kan.
  8. Awọn ìdí tí ofin ìpànìyàn yio fi jẹ mimulo jù mẹta lọ, ṣugbọn nwọn o leè jáde kúrò ninú awọn mẹta nwọn yii, Ibnu Al-Arabi Al-maaliki sọ pé: "wọn ko leè jáde kúrò ninú mẹtẹta nwọn yí botiwu korí: nítorípé dájúdaju ẹni tí o ba pidán tàbí o bú Annabi ti di Keferi (Alaigbagbọ), o si ko sínú ẹni tí o fi ẹṣin rẹ silẹ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

50 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
SQ Shqip Ede Alibania
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
FF Fulfulde Ti èdè Fulani
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
DA Dansk الدنماركية
KMR Kurmancî الكرمنجية