1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ

Hadiisi ẹ má ṣe bú atẹgun , yi e bá rí nkankan ti ko wù yín e sọ bayi pe: " irẹ Ọlọhun àwa n'bere òòrè ti wà lára atẹgun yí lọdọ rẹ àti oore tó wà nínú rẹ àti oore nkan ti wan pàá lasẹ, anwa idaabobo lọdọ rẹ níbi aburú afẹfẹ yí ati aburú nkan ti wa nínú rẹ ati aburú nkan ti wan pàá lasẹ,

عَنْ أُبَيِّ بْنِ كَعْبٍ رضي الله عنه قَالَ: قَالَ رَسُولُ اللهِ صَلَّى اللَّهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ:
«لاَ تَسُبُّوا الرِّيحَ، فَإِذَا رَأَيْتُمْ مَا تَكْرَهُونَ فَقُولُوا: اللَّهُمَّ إِنَّا نَسْأَلُكَ مِنْ خَيْرِ هَذِهِ الرِّيحِ وَخَيْرِ مَا فِيهَا وَخَيْرِ مَا أُمِرَتْ بِهِ، وَنَعُوذُ بِكَ مِنْ شَرِّ هَذِهِ الرِّيحِ وَشَرِّ مَا فِيهَا وَشَرِّ مَا أُمِرَتْ بِهِ».

Láti ọdọ Ubayy ọmọ Kahab ki Ọlọhun yọnu sí o sọ pé : òjíṣẹ Ọlọhun ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bá sọ pé : b
" ẹ má ṣe bú atẹgun , yi e bá rí nkankan ti ko wù yín e sọ bayi pe: " irẹ Ọlọhun àwa n'bere òòrè ti wà lára atẹgun yí lọdọ rẹ àti oore tó wà nínú rẹ àti oore nkan ti wan pàá lasẹ, anwa idaabobo lọdọ rẹ níbi aburú afẹfẹ yí ati aburú nkan ti wa nínú rẹ ati aburú nkan ti wan pàá lasẹ,

O ni alaafia Tirmiziy ni o gba a wa Sunanu ti Tirmidhiy - 2252

Àlàyé

anọbi kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má bà kọ fún wa láti má má bú tabi ṣepe lẹ afẹfẹ, nítorípé àṣẹda rẹ lo pá lasẹ , a má nu ikẹ wà beesini a má mú iya wà , bibu afẹfẹ tumọ sí bubu àṣẹda rẹ àti ìbínú sí idajọ rẹ, leyin náà ni anọbi kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má bà tọ wá sọ nán pé kí a Seri pàdà sí ọdọ aṣẹ̀dá rẹ ti ṣe Ọlọhun láti bèrè òòrè rẹ ati òòrè ti wan ran lọdọ rẹ , gege bí mímú ọjọ wà , ati gbígbé gígùn takọ tabo awan irúgbìn ati bẹẹ lọ , ati lati wà isora ati ààbò níbí àbúru rẹ ati àbúru ti wan firan gẹgẹ bí

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Kíkọ fún ní láti qma bù afẹfẹ, nítorípé ẹdá tí wan darí ní, eebu tí a bù yóò padà sí ọdọ asẹdá rẹ àti ẹni tí ndari rẹ, ẹdinku ninu ìmọ Ọlọhun lọkàn soso lojẹ .
  2. Iṣẹ r padà sí ọdọ Ọlọhun àti ìwà ìdáàbòbò pẹlu Rẹ̀ níbi aburú nikan toda.
  3. Atégùn le jẹ òun tí wan pa lasẹ òòrè bẹ ni wan le pa lasẹ àìdá.
  4. Ọmọ Baz sọ pé : bibu atégùn wa nínú awan apapọ ìyapa Ọlọhun , nítorí pé ẹdá tí wan pá lasẹ ní wan a fí òòrè ran bẹni wan a fí aburú ran , kò lẹtọ kí a bù , a gbọdọ sọ pé : kí Ọlọhun ṣebi lè atégùn, tàbí Ọlọhun yóò kọ atẹgun , tàbí Ọlọhun kòní fí alubarika sí atẹgun yí , tàbí inkan to ba farajọ bẹ , ṣugbọn musulumi ni láti ṣe nkán tí anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà tọ sí ojú ònà rẹ.
  5. A o tun fi wan atégùn nípa ṣíṣe eebu leewọ àti ìbáwí awan nkán tí ọ rọ mọ ooru, àti òtútù àti orún àti eruku àti àwọn nkán mí nínú awan ẹdá Ọlọhun àti ìdarí rẹ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

47 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية