1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi Ẹnikẹni ti o bá dun mọ ki Ọlọhun koo yọ nibi ìbànújẹ ọjọ igbende ko yaa se ìgbà láàyè fún ẹni tí ara ni lati san gbèsè tabi ko yá yaafi gbèsè náà fun

عَنْ أَبَي قَتَادَةَ رضي الله عنه أنَّهُ طَلَبَ غَرِيمًا لَهُ، فَتَوَارَى عَنْهُ ثُمَّ وَجَدَهُ، فَقَالَ: إِنِّي مُعْسِرٌ، فَقَالَ: آللَّهِ؟ قَالَ: آللَّهِ؟ قَالَ: فَإِنِّي سَمِعْتُ رَسُولَ اللهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ يَقُولُ:
«مَنْ سَرَّهُ أَنْ يُنْجِيَهُ اللهُ مِنْ كُرَبِ يَوْمِ الْقِيَامَةِ فَلْيُنَفِّسْ عَنْ مُعْسِرٍ أَوْ يَضَعْ عَنْهُ».

Láti ọdọ bàbá Qataada - ki Ọlọhun yọnu si - o ni oun wá ẹni tó jẹ oun lówó, o wa fi ara pamọ fún òun lẹyìn náà òun padà rí i, ni o wa sọ pé: oun wa ninu ìṣòro lati sanwo rẹ, ni o wá ṣọ pe: se o le fi orukọ Ọlọhun búra? o sọ pe: se o le fi orukọ Ọlọhun búra? o sọ pé: dájúdájú emi gbọ ti òjíṣẹ Ọlọhun (ki ike Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti nsọ pe:
"Ẹnikẹni ti o bá dun mọ ki Ọlọhun koo yọ nibi ìbànújẹ ọjọ igbende ko yaa se ìgbà láàyè fún ẹni tí ara ni lati san gbèsè tabi ko yá yaafi gbèsè náà fun".

O ni alaafia Muslim gba a wa Sọhiihu ti Muslim - 1563

Àlàyé

Abu Qotaada ará Madinah ki Ọlọhun yonu si nsọ nipa onígbèsè rẹ kan ti n fara pamọ́ fún, ni o ba ri, ni onígbèsè náà bá sọ pé: "ará o dé mi, mi o ti ni owó lati fi sàn gbèse rẹ.
Ní Abu Qotaada ki Ọlohun yọnu si bá ní kí ofi orúkọ Ọlọhun búra pé kò sí òwò lọwọ oun?
Ni o ba fi orukọ Ọlọhun búra fún pe ootọ ní òun sọ,
Ni Abu Qotaada ki Ọlọhun yọnu si bá sọ pé òun gbọ ti Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati Ọlá Rẹ má ba) ti nsọ pe:
Ẹní tí yóò bá dún mọ ki Ọlọhun sakoyọ rẹ ni bi ìbànújẹ ọjọ igbende àti ilékoko ọjọ náà ati awọn ìbẹrù rẹ ko yá se idẹra fún ẹni tí kò lágbára láti san gbèse rẹ lasiko, pẹlú pe ko fi kun àsìkò ṣiṣan tábì ki o dín kù tabi ki o bùn ní gbogbo ẹ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Fifẹ pe kí a lọ ẹnití ko lágbára láti san gbèse lára titi di igbati yóò rọ lọrun lati san, tabi ki a fún ni gbogbo ẹ tabi ki a fún ni diẹ níbẹ.
  2. Ẹnikẹni ti o bá mú ìbànújẹ kan kúrò fún olugbagbọ òdodo nínú ìbànújẹ taye, Ọlọhun yóò mú awan ìbànújẹ ọjọ igbende kuro fun Oun naa, irú iṣẹ ti a ba se ni won yóò fí san wa lẹsan.
  3. Ofin ọrọ: ni pé awan ọranyan lọ lá ju nafila (alekun ti ki se ọranyan ) lọ, sugbon ni awon apa kan asiko miran nafila le lọ lá ju ọranyan lọ, ki a bun oni gbèse ni gbese naafila ni, ki a ni suuru ati ki a lọ lára kàsí ma ti beere lọwọ rẹ ọranyan ni, naafila ni ọlá ní bi ju ọranyan lọ.
  4. Hadith náà wà fa fún ẹtọ ẹnití kò nikapa lati san gbèse, eleyi ni àwáwi, ṣugbọn ẹni tóní kapa lati san ti o lọrá lati sàn, dájúdájú o ti wa láti ọdọ Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa ba) pè ọ sọ báyi pe: "pipẹ ọlọrọ ki o to san gbèse abosi ni",

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

51 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية