1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ

عَنْ عَبْدِ اللَّهِ بنِ مسعُودٍ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قَالَ:
ذُكِرَ عِنْدَ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ رَجُلٌ نَامَ لَيْلَهُ حَتَّى أَصْبَحَ، قَالَ: «ذَاكَ رَجُلٌ بَالَ الشَّيْطَانُ فِي أُذُنَيْهِ، أَوْ قَالَ: فِي أُذُنِهِ».

Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Mashood - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé:
Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ".

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 3270

Àlàyé

Wọn darukọ ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun titi ti ilẹ fi mọ ti orun fi yọ ti kò si dide kirun ọranyan, ni Anabi ba sọ pe: oun ni arakunrin kan ti èṣù (Satani) ti tọ sí inu eti rẹ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Kikorira fifi idide kirun lóru silẹ, nitori okunfa èṣù (Satani) ni.
  2. Isọra nipa èṣù (Satani) eyi ti n ma joko sí gbogbo oju ona de ọmọniyan lati le dina laarin rẹ ati itẹle àṣẹ Ọlọhun Ọba to gbọngbọn ti O ga.
  3. Ibn Hajar sọ pé: gbólóhùn rẹ tó sọ pé: (ko dide lọ kirun) ohun ti wọn gba lero ni iran, o sì lè túmọ sí ohun ti a ti bá sábà, irun òru tabi irun ọranyan ni wọn lè gbà lero.
  4. At-Tiibiyy sọ pé: wọn da eti yan láti darukọ, bo tiẹ jẹ pe oju ni o ni ìbátan pẹlu orun, nitori ati tọkasi wíwọra orun naa, dájúdájú eti igbọrọ ni ààyè itaji, wọn si sa itọ yan; nitoripe ohun ni o rọrùn ju láti ko wọnu awọn iho, òhun sì ni ọ yara ju lati ta pọrọ wọnu isan ara, eyi ti yóò padà jogun oroju sí gbogbo orikerike ara.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

51 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية