1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Adisọkan

Hadiisi Dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro aṣiṣe àti ìgba gbé fún mi nípa awan ìjọ mí àti nkán tí wan ba jẹ wàn nípa láti ṣe

عَنْ ابْنِ عَبَّاسٍ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُمَا أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللَّهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«إنَّ اللَّهَ تَجَاوَزَ لِي عَنْ أُمَّتِي الخَطَأَ وَالنِّسْيَانَ وَمَا اسْتُكْرِهُوا عَلَيْهِ».

Lati ọdọ ọmọ Abbas kí Ọlọhun yọnu sí awan méjèjì dájú daju òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá rẹ máa ba sọ pé:
« Dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro aṣiṣe àti ìgba gbé fún mi nípa awan ìjọ mí àti nkán tí wan ba jẹ wàn nípa láti ṣe ».

قال النووي: حديث حسن رواه ابن ماجه والبيهقي وغيرهما الأربعون النووية - 39

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà nfun wa niro pé dájú dájú Ọlọhun ti se amojukuro nkán mẹta fún awan ìjọ rẹ : Alakọkọ ni : aṣiṣe, òun ni nkán tí o ba ṣẹlẹ láti ọdọ wàn lai mọn mọn se , òun ni kí muslimu ni ero pẹlu nkán tí o se , kí o wa jasi pe iṣẹ rẹ tí o se se alaba pàdé nkàn tí o yatọ sí nkan tí o gba lérò. Ẹlẹẹkeji ni : igbagbe, òun ni kí muslim se ìrántí nkán kan , ṣugbọn kí o tún gbà gbé rẹ nigbati o fẹ se , kò sí ẹsẹ fún nípa rẹ bákan náà. Ẹlẹkẹta ni : ijeni nípa se nkán, wàn le jẹ ẹrú ( ọmọ ènìyàn) nípa láti ṣe nkan tí kò fẹ se pẹlu pé koni ìkápá láti dá ijẹnipa náà padà , nígbà náà kòní sí ẹsẹ tàbí aburú kàn kan . Pẹlu ise àkíyèsí pé dájú dájú àkòrí ọrọ Hadith ni òun tí bọ nbẹ láàrin ẹrú àti Olúwa rẹ nípa ṣíṣe nkán tí wan se leewọ , ṣugbọn gbígbé nkán tí wan páni lá sẹ jù silẹ ni ti igbagbé kò tí mú aṣẹ náà kúrò, ṣugbọn tí ìwà ọdaran kan ba tí atara ṣíṣee wa ye òun tí o jẹ ẹtọ ènìyàn kò tí bọ , gẹgẹ bí kí o se sí paayan , dandan ni kí o sanwo ìtanràn emi b, tàbí kí o sesi ba mọto jẹ dandan ni fún láti san owó ìtanràn .

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Gbígba ààyè ikẹ Ọlọhun - tí o gbongbon tí o gajulọ - àti aanu rẹ fún awán ẹrú rẹ nigbati o gbé ẹsẹ kúrò fún wan tí ẹsẹ tàbí ìyapa Ọlọhun ba ṣẹlẹ láti ọdọ wan lórí awán isesi mẹta yíì .
  2. Ọlá Ọlọhun lórí anọbi Muhammad kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba àti ijọ rẹ.
  3. Gbígbé ẹsẹ kúrò kò túmọ sí pé gbígbé ìdájọ kúrò tàbí
  4. Majẹmu ní láti wa fún gbígbé ese kúrò fún ní latara ijẹni nípa, bíi kìí ẹni tí wan jẹ nípa ni ìkápá láti ṣe nkán tí wan fí se idẹruba fún .

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

59 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
BM Bambara البامبارية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
DA Dansk الدنماركية
RN Kirundi الكيروندي
KMR Kurmancî الكرمنجية
MS Bahasa Melayu الملايو