عَنْ أَبِي مُوسَى رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ قَالَ: قَالَ النَّبِيُّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ:
«مَثَلُ الَّذِي يَذْكُرُ رَبَّهُ وَالَّذِي لاَ يَذْكُرُ رَبَّهُ، مَثَلُ الحَيِّ وَالمَيِّتِ»، ولفظ مسلم: «مَثَلُ الْبَيْتِ الَّذِي يُذْكَرُ اللهُ فِيهِ، وَالْبَيْتِ الَّذِي لَا يُذْكَرُ اللهُ فِيهِ، مَثَلُ الْحَيِّ وَالْمَيِّتِ».

Láti ọdọ baba Musa - kí Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pe:
"Àpèjúwe ẹniti nrántí Olúwa rẹ ati ẹnití kò rántí Olúwa rẹ da gege bi alààyè ati òkú ni ", gbólóhùn ti Muslim ni" Àpèjúwe ile ti wọn ti nranti Ọlọhun, ati ile ti wọn kò rántí Ọlọhun níbẹ o da gẹgẹ bí alaayè ati òkú ".

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 6407

Àlàyé

Anọbi ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má bà nsalaye iyatọ to wa láàrin ẹni ti nranti Ọlọhun ti o ga jù ati ẹni tí kò rántí Rẹ, ati pé gẹgẹ bí iyatọ tó wà láàrin àlàyé ati òkú ni bi iwulo rẹ ati didara irisi rẹ, àpèjúwe ẹni ti nranti Olùwà rẹ ọ da gẹgẹ bí aláayè ti ìta rẹ gbé ẹṣọ jáde pẹlu imọlẹ iseni , ati inú rẹ pẹlu imọlẹ ìmọ, ìwúlò n'bẹ lára rẹ, àpèjúwe ẹni tí kò rántí Ọlọhun o da gẹgẹ bí òkú ti ìta rẹ ti da ṣẹlẹ ti inú rẹ sí ti bajẹ, bẹẹ ni kòsí ìwúlò kan kan lára rẹ mọn.
Bẹẹ náà ni ilé wan royin rẹ pẹlu isemi (aláayè) ti awan olùgbé rẹ bá nranti Ọlọhun, ti wan ba rántí Ọlọhun a jẹ pé òkú ni ile náà kúrò níbi ìrántí Ọlọhun, ti wan ba lo aláayè ati òkú lati fí royin ile ẹni ti o gbe bẹ ni wan fi ọrọ bawo.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ìṣe ni ojúkòkòrò lori ìrántí Ọlọhun ati isọni lára kuro nibi ìgbà gbéra
  2. Ìrántí ni isemi emi bẹẹ ni emi ni isemi ará.
  3. Ninu imọna ati ìlànà Anọbi ki ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ má ba ni lílò òwe tabi àkàwé lati mu ìtumọ ọrọ Simoni.
  4. An-Nawawi sọ pé: fifẹ ki a má darukọ Ọlọhun ti o ga jùlọ ninu ile wà níbẹ̀, ati pe ilé ko gbọdọ pa ṣofo ní bi ìrántí ati idaruko Ọlọhun.
  5. An-Nawawiy sọ pé: o wa ninu hadith náà pé gígùn ẹmi lórí itẹle aṣẹ Ọlọhun ohun ti o lọ lá ni bo tilẹ jẹ pé òkú ngbé rà lọsí bi tó lòó rè ni, nítorípé aláayè na yóò padà ló dára pọ mọ ti yóò lè kun jù lọ latara awon iṣẹ itẹle aṣẹ Ọlọhun ti o ti se.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

51 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية