1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi o ṣe aluwala fun wọn ni aluwala Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-

عَنْ يحيى بنِ عُمَارةَ المَازِنِيِّ قَالَ:
شَهِدْتُ عَمْرَو بْنَ أَبِي حَسَنٍ سَأَلَ عَبْدَ اللَّهِ بْنَ زَيْدٍ، عَنْ وُضُوءِ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ فَدَعَا بِتَوْرٍ مِنْ مَاءٍ، فَتَوَضَّأَ لَهُمْ وُضُوءَ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، فَأَكْفَأَ عَلَى يَدِهِ مِنَ التَّوْرِ، فَغَسَلَ يَدَيْهِ ثَلاَثًا، ثُمَّ أَدْخَلَ يَدَهُ فِي التَّوْرِ، فَمَضْمَضَ وَاسْتَنْشَقَ وَاسْتَنْثَرَ، ثَلاَثَ غَرَفَاتٍ، ثُمَّ أَدْخَلَ يَدَهُ فَغَسَلَ وَجْهَهُ ثَلاَثًا، ثُمَّ غَسَلَ يَدَيْهِ مَرَّتَيْنِ إِلَى المِرْفَقَيْنِ، ثُمَّ أَدْخَلَ يَدَهُ فَمَسَحَ رَأْسَهُ، فَأَقْبَلَ بِهِمَا وَأَدْبَرَ مَرَّةً وَاحِدَةً، ثُمَّ غَسَلَ رِجْلَيْهِ إِلَى الكَعْبَيْنِ.

Lati ọdọ Yahya ọmọ 'Umaaroh Al-Maaziniy o sọ pe:
Mo ri ti Amru ọmọ Abu Hasan bi Abdullahi ọmọ Zaid leere nipa aluwala Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni o ba beere fun igba kan ti omi wa ninu ẹ, o ṣe aluwala fun wọn ni aluwala Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-, o da omi si ọwọ rẹ lati inu igba, o fọ ọwọ rẹ mejeeji lẹẹmẹta, lẹyin naa o ti ọwọ rẹ bọ inu igba, o fi omi yọ ẹnu o si fa a simu, O si fa a sita, ni gẹẹ mẹta, lẹyin naa o ti ọwọ rẹ bọ ọ, o si fọ oju rẹ lẹẹmẹta, lẹyin naa o fọ ọwọ rẹ mejeeji ni ẹẹmeji titi de igunpa mejeeji, lẹyin naa o ti ọwọ rẹ bọ ọ, o si pa ori rẹ, o gbe mejeeji lọ si ẹyin ati ṣíwájú ni ẹẹkan, lẹyin naa, o fọ ẹsẹ rẹ mejeeji titi de kokosẹ

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 186

Àlàyé

Abdullahi ọmọ Zaid- ki Ọlọhun yọnu si i- ṣàlàyé bi aluwala Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe ri, pẹlu aworan ti iṣẹ, Ni o ba beere fun igba kekere kan ti omi wa ninu ẹ, O kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ pẹlu fifọ ọwọ rẹ mejeeji, lẹyin naa o tẹ igba naa o si da omi, o si fọ mejeeji lẹẹmẹta si ita igba naa, Lẹyin naa o ti ọwọ rẹ bọ inu igba, o si bu omi gẹẹ mẹta, ti o n yọ ẹnu ninu gbogbo gẹẹ kọọkan ti o si n fin omi si imu ti o si n fin in sita pada, Lẹyin naa o bu omi ninu rẹ ti o si fọ oju rẹ lẹẹmẹta, Lẹyin naa o bu omi ninu rẹ ti o si fọ ọwọ rẹ mejeeji titi de igunpa mejeeji ni ẹẹmeji ẹẹmeji, Lẹyin naa, o ti ọwọ rẹ mejeeji bọ inu igba ti o si pa ori rẹ pẹlu ọwọ rẹ lati ibi ti irun rẹ ti bẹ̀rẹ̀ titi ti o fi de ipakọ rẹ ni oke ọrun, lẹyin naa, o da mejeeji pada titi o fi de aaye ti o ti bẹ̀rẹ̀ nibẹ, Lẹyin naa, o fọ ẹsẹ rẹ mejeeji pẹlu kokosẹ mejeeji.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. ki olùkọ́ maa tọ ọna to sunmọ julọ debi agbọye ati irinlẹ imọ, ati pe ninu ìyẹn ni ikọnilẹkọọ pẹlu iṣẹ.
  2. Ṣíṣe pipaara lẹẹmẹta lẹtọọ ni apakan awọn orikee aluwala ati ẹẹmeji ni apakan rẹ, ati pe eyi ti o jẹ dandan ni ẹẹkan.
  3. Jijẹ dandan titotẹlera laaarin awọn orikee aluwala gẹgẹ bi o ṣe wa ninu hadiisi naa.
  4. Aala oju ni ibi ti irun ori ti n hù ti a ba saaba titi de nnkan ti o sọkalẹ ninu irun-agbọn ati agbọn ni òró, ati lati eti kan si eti keji ni ìbú.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

59 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
SO Soomaali Ti èdè Somalia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
IT Italiano Ti ede ilu Italy
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
KMR Kurmancî الكرمنجية