1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Adisọkan

Hadiisi ẹru kan ko ni se ibasiri fún ẹrú kan láyé nbi ayaafi ki Ọlọhun se ibasiri fún un ni ọjọ igbende

عَنْ أَبِي هُرَيْرَةَ رضي الله عنه عَنِ النَّبِيِّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«لَا يَسْتُرُ عَبْدٌ عَبْدًا فِي الدُّنْيَا إِلَّا سَتَرَهُ اللهُ يَوْمَ الْقِيَامَةِ».

Lati ọdọ Abu Hurayrah - ki Ọlọhun yọnu si i - lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o sọ pe:
"ẹru kan ko ni se ibasiri fún ẹrú kan láyé nbi ayaafi ki Ọlọhun se ibasiri fún un ni ọjọ igbende".

O ni alaafia Muslim gba a wa Sọhiihu ti Muslim - 2590

Àlàyé

Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) n salaye fun wa pé musulumi kan ko ni bo asiri ọmọ Iya rẹ tó jẹ musulumi nipa àlámọ̀rí kan ninu awọn àlámọ̀rí, ayaafi ki Ọlọhun bo asiri rẹ ni ọjọ igbende, iran iṣẹ ti a ba se náà ni a o gba ẹsan rẹ, yóò wa jasipe bibo àṣírí Ọlọhun fún un ni pé yóò bo asiri awọn laifi rẹ àti àwọn ẹsẹ rẹ lati máa ṣe itanka rẹ lọdọ awọn ti wọn wani ibi gbangba Al-kiyaoma, o si le je pe bibo asiri rẹ ni ki Ọlọhun má ṣe iṣiro rẹ tabi ki o má ti ẹ mẹnu kaan rárá.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Wiwa ni ibamu sí ilana ẹṣin pe ki a se bibo àṣírí fún musulumi nigbati o bá wu iwa ẹsẹ kan, pẹlu ki a tako iwa naa, ki a sì máa fún un ni ìkìlọ̀ ati imọran, ki a sì máa fi Ọlọhun fún un ni ifoya, sugbọn tí o bá wà nínú àwọn alaburu ati àìda ti wọn nse ẹsẹ ati iwa poki ni gbangba, kò tọ láti bo asiri wọn, nitori ki a bo asiri wọn yóò jẹ ki wọn maa ni ìgboyà láti máa dá ẹsẹ, a ni lati gbe ọrọ wọn lọ sí ọdọ awọn apàṣẹ, koda ki o jasipe a darukọ rẹ, nitoripe oun náà ti se afihan ìyapa ati ìwà poki rẹ ati ẹsẹ rẹ.
  2. Iseni lójúkòkòrò láti máa bo asiri ẹlòmíràn.
  3. Ninu ìwúlò biboni lasiri : Fifun ẹlẹsẹ ní ànfàaní igbalaaye láti yẹ ara rẹ wò kí o si ronú piwada sí ọdọ Ọlọhun; nitoripe ṣiṣe ikede laifi ati ibi ti enikan kùsí wa lara itan ibajẹ ka, aa si maa ba ojú ọjọ àwùjọ jẹ, bẹẹ ni aa maa se awọn eniyan loju kòkòrò lati máa ṣe iru rẹ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

50 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية