عَنْ جَابِرٍ رضي الله عنه قَالَ: سَمِعْتُ النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَبْلَ وَفَاتِهِ بِثَلَاثٍ يَقُولُ:
«لَا يَمُوتَنَّ أَحَدُكُمْ إِلَّا وَهُوَ يُحْسِنُ بِاللهِ الظَّنَّ».

Lati ọdọ Jaabir - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: mo gbọ tí Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - sọ ni ọdun mẹta síwaju koto fi ayé silẹ báyi pé:
"Ẹnikan ninu yin ko gbọ ku ayaafi ki o ni àbá daada si Ọlọhun".

O ni alaafia Muslim gba a wa Sọhiihu ti Muslim - 2877

Àlàyé

Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) gba musulumi níyànjú lati má kùú ayaafi ki o ni àbá daada si Ọlọhun pẹlu ki o fi abala inireti sọdọ Ọlọhun leke nígbàtí nba pọka iku lọwọ n'ireti pe Ọlọhun Yóò ṣekẹ rẹ yóò ṣe amojukuro fún un; nitoripe ifoya ni nkan ti wọn beere fún ki a le ri iṣẹ se daada, ìṣesí un kii se iṣesí iṣẹ ṣiṣe, nkan ti wọn fẹ nibẹ ni ki ireti borí.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) nifẹ si ki o máa ṣe itọsọna fún àwọn ọmọlẹyin rẹ ati àánu rẹ tó pọ sí wọn ni gbogbo iṣesí wọn; titi o fi de ààrẹ ti o se gbẹyin o ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ìjọ rẹ o si ntọka wọn sí awọn ọna ìgbàlà tabi àkóyọ.
  2. At-tiibiyy sọ pé: ẹ se iṣẹ yín daada ni sinyin ki aba yin si Ọlohun le da nigbati iku ba dé, nitoripe ẹni tí iṣẹ rẹ ò ba dáa siwaju ki iku to de aba rẹ konii da nigbati iku ba dé.
  3. Èyí tí o pe ju ni iṣẹ fún ẹrú ni iṣẹ to dọgba ireti ati ifoya, ati ki ìfẹ lékè, ìfẹ ni nkan imugun, ireti ni ẹni ti ndari re, ifoya ni ẹni ti nwa a, Ọlọhun ni yóò mú ni dé bẹ pẹlu aanu Rẹ àti ọrẹ Rẹ.
  4. o da fún ẹni tí o ba sunmọ ent o pọ k'a iku lọwọ kí o máa fi ìrètí lékè fún ati ìní ẹrọ to dá sí Ọlọhun, ninu hadith yi Anọbi kí ikẹ Olohun àti Ọlá Rẹ má dájú dájú o sọ bẹ nigbati ti o ku odun mẹta ti yóò ku.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

50 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية