1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ

Hadiisi Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó

عَنْ أبي سَعيدٍ الخُدريَّ رضي الله عنه قال: قال رسولُ الله صلَّى الله عليه وسلم ِ:
«إزْرَةُ المُسْلمِ إلى نصفِ السَّاق، وَلَا حَرَجَ -أو لا جُنَاحَ- فيما بينَهُ وبينَ الكعبينِ، وما كان أسفلَ منَ الكعبين فهو في النار، مَن جرَّ إزارَهُ بطرًا لم يَنْظُرِ اللهُ إليه».

Láti ọdọ bàbá Saheed Al - Khudiryy kí Ọlọhun yọnu sí o sọ pé: Òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá Rẹ má bà s'ọpe :
« Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó»

O ni alaafia Abu Daud ati Ibnu Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa Sunanu ti Abu Daud - 4093

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà tí se alaye pé dajudaju sokoto muslim l'ọkunrin ni awan ìsesí mẹta , sokoto ni òun tí yóò bọ ìdajì isalẹ ará ọkunrin: Alakọkọ ni : Èyí tí wan fẹ ni kí o gùn fẹ ìdajì ojúgun rẹ. Ẹlẹẹkeji ni : Èyí tí o lẹtọ lai sí kikorira níbẹ ni pé kí o kọja ìdajì ojúgun titi de kókósẹ méjèjì ' òun náà ni egún gùn méjì Ẹlẹkẹta : èyí tí o jẹ èèwọ pẹlu pé kí o gùn kọja kókósẹ méjèjì, ipaya sí wa lórí rẹ pé kí inan má lọ ṣẹlẹ sí , tí o ba se pé o se bẹ ni tí moto moto àti ìyá yọ pọra àti ikọja aala Ọlọhun kòní siju aanu wó .

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ìròyìn yí àti ìlérí yí da wa lọtọ fún awan ọkunrin ṣugbọn awan obìnrin , wàn se adayanri wàn kúrò níbẹ , nítorípé wàn tí pa wàn lasẹ láti bọ gbogbo ará wàn .
  2. Gbogbo nkán tí o ba le bọ ìdajì isalẹ ará ni wàn pé ni Izar tàbí , gẹgẹ bí sókótó, àti aṣọ àti nkan mí tí o yatọ sí awan méjèjì, o sí ti wa nínú awàn ìdájọ òfin ẹṣin tí wan tí sọ nípa rẹ nínú Hadith yí .

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

44 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية