1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Adisọkan

Hadiisi Tí wan ba gbé òkú kalẹ tí awàn ènìyàn (Ọkunrín ) gbé si gbee sí ọrùn wan , tí o ba se pé ẹniire ni yóò sọpe : ẹtete tí mí síwájú,

عَن أَبِي سَعِيدٍ الخُدْرِيَّ رَضِيَ اللَّهُ عَنْهُ أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ قَالَ:
«إِذَا وُضِعَتِ الجِنَازَةُ وَاحْتَمَلَهَا الرِّجَالُ عَلَى أَعْنَاقِهِمْ فَإِنْ كَانَتْ صَالِحَةً قَالَتْ: قَدِّمُونِي، وَإِنْ كَانَتْ غَيْرَ صَالِحَةٍ قَالَتْ: يَا وَيْلَهَا أَيْنَ يَذْهَبُونَ بِهَا؟ يَسْمَعُ صَوْتَهَا كُلُّ شَيْءٍ إِلَّا الإِنْسَانَ، وَلَوْ سَمِعَهُ صَعِقَ».

Láti ọdọ bàbá Sa'eed Al-kuhdiry kí Ọlọhun yọnu sí dájú dájú òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá Rẹ má bà s'ọpe:
« Tí wan ba gbé òkú kalẹ tí awàn ènìyàn (Ọkunrín ) gbé si gbee sí ọrùn wan , tí o ba se pé ẹniire ni yóò sọpe : ẹtete tí mí síwájú, tí o ba se pé kìí se eniire yóò sọ pé : ha o má se fún òunh nibo ni wan ngbé òunh lọ bayi? Gbogbo nkán ni yóò má gbọ òunh rẹ ayaafi ènìyàn nìkan, tí ènìyàn a gbọ òunh rẹ ní wan ba daku ni » .

O ni alaafia Bukhaariy gba a wa Sọhiihu ti Bukhaariy - 1314

Àlàyé

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti Ọlá rẹ máa ba fún wa niro pé tí wan ba gbé òkú kalẹ lórí ibùsùn, tí awàn eniyan l'ọkunrin sí gbé sórí ọrùn wan , tí o ba ṣepe ẹniire ni yóò sọ pé: etimi síwájú sí bí idẹra tí o wa níwájú rẹ, tí kí baa se eniire yóò parí wo pẹlu òunh tí arà kọ pé : ìparun tí dé ba òun nibo ni wan ngbé òunh lọ yì ?! Nitori ìyá tí o tiri ni iwájú rẹ, gbogbo nkán ni yóò gbọ òunh rẹ ayaafi ènìyàn, tí ènìyàn ba gbọ kò bà daku lẹkan náà latara lilagbara nkán to fí etí ará rẹ gbọ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Okú tí o jẹ ẹniire yóò máa ri awan ìfun ni ní ìró ayọ síwájú kí wan to ṣin , bẹẹ ni alaigbagbọ yóò máa tara párá, yóò sí máa ri Idakeji òun tí ẹniire rí .
  2. Díẹ nínú awàn òunh ni awan ẹda tí o yatọ sí ènìyàn má ngbọ , bẹẹ sí ní awan ènìyàn kòní le gbọ
  3. Ìlànà anọbi ni kí a gbe òkú ṣì ọrùn awan ọkunrin lai kii se awan obìnrin, nítorípé anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá rẹ máa ba tí kọ fún awan obìnrin láti má máa tẹlé òkú lọ itẹ.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

45 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية