1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Adisọkan

Hadiisi Arakunrin kan wa si ọdọ Anabi Ọlọhun -ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a-, o si ba a sọrọ nipa ọrọ kan, o sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ, ti iwọ anabi si fẹ. ” Nígbà náà ni Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, wí pé: “ṣé iwọ o fi mí ṣe bakannaa pẹlu Ọlọ́run ni? Sọ pé: Ohunkóhun tí Ọlọ́run nìkan ṣoṣo bá fẹ́”

عَنِ ابْنِ عَبَّاسٍ رضي الله عنهما:
أَنَّ رَجُلًا أَتَى النَّبِيَّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ، فَكَلَّمَهُ فِي بَعْضِ الْأَمْرِ، فَقَالَ: مَا شَاءَ اللهُ وَشِئْتَ، فَقَالَ النَّبِيُّ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ: «أَجَعَلْتَنِي لِلَّهِ عَدْلًا؟ قُلْ: مَا شَاءَ اللهُ وَحْدَهُ».

Lati ọdọ Ibn Abbas, ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji:
Arakunrin kan wa si ọdọ Anabi Ọlọhun -ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a-, o si ba a sọrọ nipa ọrọ kan, o sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ, ti iwọ anabi si fẹ. ” Nígbà náà ni Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, wí pé: “ṣé iwọ o fi mí ṣe bakannaa pẹlu Ọlọ́run ni? Sọ pé: Ohunkóhun tí Ọlọ́run nìkan ṣoṣo bá fẹ́”.

Isnaadu rẹ daa Ibnu Maajah ati Nasaa'iy ni wọn gba a wa nínú al-Kubrọ, ati Ahmad As-Sunanul Kubrọ ti An-Nasaaiy - 10759

Àlàyé

Arakunrin kan wa si ọdọ Anabi, o si ba a sọro nipa ọrọ ara rẹ, lẹ́yìn naa o sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ ati ohunkohun ti o ba fẹ”, Ojiṣẹ Ọlọhun, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a, bá tako ọrọ yii o si sọ fun un pe sise idapọ fifẹ ẹda pẹ̀lú fifẹ Ọlohun pẹlu lẹ́tà “waw” jẹ ìsẹbọ kekere si Ọlọhun, ko si lẹtọọ fun Musulumi lati sọ ọ, Lẹ́yìn náà, ó ṣamọ̀nà rẹ̀ sí ọ̀rọ̀ òtítọ́ náà pé: “Ohunkóhun tí Ọlọ́hun nìkan ṣoṣo ba fẹ́,” nítorí náà ó maa ya Ọlọ́hun sọ́tọ̀ nínú ìfẹ́ Rẹ̀, kò sì nii so fifẹ ẹni kankan mọ ọn pẹlu èyíkéyìí ninu iran asopọ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. O jẹ ewọ lati sọ pe: “Ohun ti Ọlọhun fẹ ati ohun ti ìwọ naa ba fẹ,” ati ohun ti o jọ ọ ninu nnkan ti asopọ fifẹ ẹru mọ fifẹ ti Ọlọhun n bẹ nibẹ pẹlu lẹ́tà WAW; torí pé ẹbọ kekere ni.
  2. Ijẹ ọranyan kikọ ohun burúkú.
  3. Ojiṣẹ Ọlọhun, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – daabo bo ọgbà taohid, o si di àwọn ọ̀nà ẹbọ.
  4. Nigba ti a ba n kọ aburu, o dara ki a dari ẹni ti a n pe si ibomiran ti o yẹ to si tọ́ lati fi kọ́ṣe Anọbi- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -.
  5. Idapọ laaarin ọrọ rẹ- ki ikẹ ati ọla Ọlọhun o maa ba a- ninu Hadiisi yii: “Ohunkohun ti Ọlọhun nikan ṣoṣo ba fẹ” ati ọrọ rẹ ninu Hadiisi miiran: “ Sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ, lẹyin naa ohunkóhun tí ìwọ naa ba fẹ", ni pe o ni ẹ̀tọ́ ki èèyàn sọ pe: "Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ, lẹyin naa ohunkóhun tí ìwọ naa ba fẹ", ṣùgbọ́n èyí tí ó ni ọlá jù ni gbólóhùn: "Ohunkohun ti Ọlọhun nikan ba fẹ".
  6. O lẹtọọ lati sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun ba fẹ, lẹyin naa ohunkóhun tí o ba fẹ,” ṣugbọn o dara julọ lati sọ pe: “Ohunkohun ti Ọlọhun nikan ba fẹ”.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

58 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
SO Soomaali Ti èdè Somalia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
IT Italiano Ti ede ilu Italy
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
KMR Kurmancî الكرمنجية