1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin

عن أنس رضي الله عنه أن النبي صلى الله عليه وسلم قال:
«جَاهِدُوا المشركين بأموالكم وأنفسكم وألسنتكم».

Láti ọdọ Anas - ki Ọlọhun yọnu si i - dájúdájú Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pé:
"E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin".

O ni alaafia رواه أبو داود والنسائي وأحمد Sunanu ti Abu Daud - 2504

Àlàyé

Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bà) pa wà lasẹ lati gbógun ti alaigbagbọ, ki a sì ná ìgbìyànjú láti dájú kọ won pẹlu gbogbo ọnà tí a ni ìkápá le lórí nítorí kì gbólóhùn ati ọrọ Ọlọhun le wa loke, nínú ìgbìyànjú náà ni:
Alakọkọ: nina owó àti dukia lati fi gbógun ti won, bí rírà nkan ijagun, ati ìnáwó lórí awon jagunjagun ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Ẹlẹkeji: ki a jàdé pẹlu emi ati ará lati lọ pàdé won ati lati da won pàdà.
Ẹlèkẹta: pẹlu pípé won síbi ẹṣin Islam yi pẹlú ahán, ati ifi idi ọrọ ati ẹri rinlẹ fún won ati ijagbe mọ won ati ìfun won lèsi.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. iseni lojúkòkòrò lati gbógun ti olusẹbọ pẹlú ẹmi ati owó àti ahán, ni ibámu sí Olukaluku bá ṣè ni agbára àti ìkápá mọ, ati pé dájúdájú ìjagun sójú ọnà Ọlọhun kii ṣe fífi ẹmi jà nikan ni.
  2. Ipani lasẹ lati jagun jẹ ọranyan, o le jẹ ọranyan ojúlówó fún gbogbo musulumi, o sí le jẹ òranyàn tito.
  3. Olohun se ogun jija ni òfin ẹṣin nítorí àwọn nkán nkán ninu rẹ ni: Alakọkọ: Gbigbogun ti ise ẹbọ ati awon olusẹbọ, nítorípé Ọlọhun Ọba ko ni gba ise ẹbọ laye laye. Ẹlẹkeji: Mímú awọn iṣoro àti wàhálà ti nkọ di ojú ọnà ìpepé sí ojú ònà Ọlọhun kúrò. Ẹlèkẹta: Didaabo bó ìgbàgbọ àti adisọkan nibi gbogbo nkan ti o ba yàtọ sí. Ẹlẹkẹrin : Didaabo bó awon musulumi ati awọn ilu won, Omoluabi won ati dukia (awon nkan ini won).

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

48 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
BN বাংলা Èdè Bangali
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية