عَنْ أَنَسِ بْنِ مَالِكٍ رضي الله عنه قَالَ: قَالَ رَسُولُ اللهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ:
«مَنْ عَالَ جَارِيَتَيْنِ حَتَّى تَبْلُغَا جَاءَ يَوْمَ الْقِيَامَةِ أَنَا وَهُوَ» وَضَمَّ أَصَابِعَهُ.
المزيد
Lati ọdọ Anas ọmọ Maalik, ki Ọlọhun bá wa yọnu si i, o sọ bayi pe: Òjíṣẹ Ọlọhun - Ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba - sọ bayi pe:
"Ẹnikẹni ti ó bá ṣamojuto ọmọ obinrin meji tabi tí ó tọ́ wọn dagba titi ti wọ́n fi di ẹni ọkunrin, irufẹ ẹni bẹẹ yóò wá ní ọjọ igbende ti èmi rẹ̀ yóò wà papọ̀" Anọbi pa ọmọnika rẹ papọ̀ mọ́nrawọn.