1. Ilé
  2. Àwọn ìsọ̀rí
  3. Fik'hu ati ìpìlẹ̀ rẹ

Hadiisi Dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji si deedee ejika rẹ mejeeji ti o ba ti bẹ̀rẹ̀ irun,

عَن ابْنِ عُمَرَ رضي الله عنهما:
أَنَّ رَسُولَ اللَّهِ صَلَّى اللهُ عَلَيْهِ وَسَلَّمَ كَانَ يَرْفَعُ يَدَيْهِ حَذْوَ مَنْكِبَيْهِ إِذَا افْتَتَحَ الصَّلَاةَ، وَإِذَا كَبَّرَ لِلرُّكُوعِ، وَإِذَا رَفَعَ رَأْسَهُ مِنَ الرُّكُوعِ، رَفَعَهُمَا كَذَلِكَ أَيْضًا، وَقَالَ: «سَمِعَ اللَّهُ لِمَنْ حَمِدَهُ، رَبَّنَا وَلَكَ الحَمْدُ»، وَكَانَ لاَ يَفْعَلُ ذَلِكَ فِي السُّجُودِ.

Lati ọdọ Ọmọ Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji-:
Dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji si deedee ejika rẹ mejeeji ti o ba ti bẹ̀rẹ̀ irun, ati ti o ba ti kabara fun rukuu, ati ti o ba gbe ori rẹ dide lati rukuu, o maa gbe mejeeji bákannáà, o si maa sọ pé: "Sami'alloohu liman hamidaHu, Robbanaa wa laKal hamdu", ko ki n ṣe bẹẹ nibi iforikanlẹ.

O ni alaafia Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni Sọhiihu ti Bukhaariy - 735

Àlàyé

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji soke nibi aaye mẹta ninu irun ni iwájú ejika ti o ṣe pe: Oun ni ibi ti egungun ejika ati apa ti papọ.
Aaye akọkọ: Ti o ba ti bẹ̀rẹ̀ irun nibi kikabara iwọ irun.
Ikeji: Ti o ba ti kabara fun rukuu.
Ikẹta: Ti o ba ti gbe ori rẹ sókè lati rukuu, ti o wa sọ pe: Sami'alloohu liman hamidaHu Robbanaa wa laKal hamdu.
Ko ki n gbe ọwọ rẹ mejeeji sókè nibi ìbẹ̀rẹ̀ fifi ori kanlẹ, tabi nibi gbigbe ori sókè lati ibẹ.

Lára àwọn àǹfààní hadiisi naa

  1. Ninu awọn ọgbọn ti o n bẹ fun gbigbe ọwọ mejeeji soke nibi irun ni pe o jẹ ọṣọ fun irun ati igbetobi fun Ọlọhun- mimọ ni fun Un-.
  2. Gbigbe ọwọ rẹ mejeeji soke fi ẹsẹ rinlẹ lati ọdọ rẹ̀ - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nibi aaye ikẹrin gẹgẹ bi o ṣe wa ninu ẹgbawa Abu Hamid As-Saa'idiy lọdọ Abu Daud ati ẹni ti o yàtọ̀ si i, oun ni nibi idide lati ataya akọkọ nibi irun oni rakah mẹta ati mẹrin.
  3. O fi ẹsẹ rinlẹ bakannaa lati ọdọ rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe o maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji si deedee eti rẹ mejeeji laini fi ọwọ kan an gẹgẹ bi o ṣe wa ninu ẹgbawa Maalik ọmọ Al-Huwairith ninu sọhihu mejeeji pé: "Dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ti o ba kabara o maa n gbe ọwọ rẹ mejeeji sókè titi tí o maa fi ṣe deedee eti rẹ mejeeji pẹlu wọn"
  4. Adapọ laaarin ṣíṣe Sami'alloohu liman hamidaHu ati Robbanaa wa laKal hamdu jẹ ti imam ati oluda-irun-ki nìkan, ṣùgbọ́n ero ẹyin imam maa sọ pé: Robbanaa wa laKal hamdu.
  5. Sisọ pe: "Robbanaa wa laKal hamdu" lẹyin rukuu ni alaafia lati ọdọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pe awọn ọna mẹrin kan ni a le gba sọ ọ, ati pe eleyii jẹ ọkan ninu rẹ, eyi ti o daa julọ ni ki ọmọniyan tọ ipasẹ àwọn agbekalẹ yii, ki o si mu eyi wa ni ẹẹkan, ati òmíràn wa nigba mii.

Ṣíṣe àfihàn àwọn ìtumọ̀ sí èdè mìíràn

58 Èdè
EN English Èdè Gẹ̀ẹ́sì
UR اردو Èdè Urdu
ES Español Èdè Sípéènì
ID Indonesia Èdè Indonéṣíà
UG ئۇيغۇرچە Èdè Uyghur
BN বাংলা Èdè Bangali
FR Français Èdè Faransé
TR Türkçe Èdè Tọ́kì
RU Русский Èdè Rọ́ṣíà
BS Bosanski Èdè Bosnia
SI සිංහල Èdè Sinhala
HI हिन्दी Èdè India
ZH 中文 Èdè Ṣáínà
FA فارسی Èdè Páṣíà
VI Tiếng Việt Èdè Vietnamese
TL Tagalog Èdè Tagalog
KU Kurdî Ti Kurdish
HA Hausa Èdè Hausa
PT Português Ti Pọtuga
ML മലയാളം Malayalam
TE తెలుగు Èdè Telgu
SW Kiswahili Ti èdè Sawahili
TA தமிழ் Tamil
MY မြန်မာ Burmese
TH ไทย Thai
DE Deutsch Ede Jamani
PS پښتو Pashto
AS অসমীয়া Assamese
SQ Shqip Ede Alibania
SV Svenska Titi Sweden
AM አማርኛ Ìtumọ̀ sí èdè Amharic
NL Nederlands Ìtumọ̀ sí èdè Dutch
GU ગુજરાતી Titi èdè Gujarat
KY Кыргызча Ti èdè Kyrgyz
NE नेपाली Ti èdè ìlú Nepal
LT Lietuvių Ti èdè Lithuania
PRS دری Ti èdè Dari
SR Српски Ti èdè ìlú Serbia
SO Soomaali Ti èdè Somalia
TG тоҷикӣ Ti èdè ìlú Tajikistan
RW Kinyarwanda Ti èdè Rwanda
RO Română Ti èdè ìlú Romania
HU Magyar Ti èdè ilu Hungary
CS Čeština Ti èdè Czech
MOS Moore الموري
MG Malagasy Ti ede Madagascar
OM Oromoo Ti èdè ẹ̀yà Oromo
KN ಕನ್ನಡ Ti èdè Kannada
WO Wolof الولوف
AZ Azərbaycan Ti ede Azerbaijan
UZ O‘zbek Ti èdè ilu Uzbekistan
UK Українська Ti èdè ìlú Ukraine
KA ქართული الجورجية
MK Македонски المقدونية
KM ភាសាខ្មែរ الخميرية
PA ਪੰਜਾਬੀ البنجابية
MR मराठी الماراثية
KMR Kurmancî الكرمنجية